Bukola akinade biography of albert



Bukola akinade biography of albert

  • Bukola akinade biography of albert einstein
  • Bukola akinade biography of albert lea
  • Biography of albert einstein
  • Bukola akinade biography of albert hall
  • Bukola akinade biography of albert lea.

    Bukola Akinade Senwele Jesu: Warisi, Zah zuh, Galalala, wo àwọn àṣàkàṣa tí Senwele ní kò bá òfin Ọlọ́run mu

    Oríṣun àwòrán, Senwele Jesu

    "Eleyi to maa n bi mi ninu ju laye ati ọrun ni ki wọn ti pe ẹ koo wa kọrin too ti ko elegbe ati onilu ẹ lẹyin too tun wa n fi ẹnu tun nkan ti onilu filu sọ sọ sita.

    Waa tun wa ko bii elegbe mẹta mẹrin ki wọn maa pariwo tun nkan ti onilu sọ sọ.

    Ariwo a wa pọ lọ rẹpẹtẹ ko ni jẹ ka gbọ nkan ti Ọlrun ran si wa.

    K'olorin maa kọrin kiwọ naa maa ṣe 'Ọba baba digbẹ digbẹ n gbẹ" o maa n run mi ninu".

    Toun ti imura awọn to n gberin lẹyin ga wọn lo bu ẹnu atẹ lu to ni gbogbo iwa yii ko si laarin awọn olorin to gbe iṣẹ orin ẹmi le awọn lọwọ.

    "Igba too mọ pe o le da gbogbo ẹ ṣe, ki lo ko wọn lẹyin si".

    Ki ni Senwele ri to fi ṣe fidio yii sita?

    Gbajugbaja olorin ẹmi, Bukola Akinade figbe yii bọ ẹnu loju opo ayelujara rẹ pe kini kan wa to n dun oun lọkan.

    Oríṣun àwòrán, Senwele Jesu

    "Ráda